𝗡𝗔𝗠𝗘 𝗢𝗙 𝗛𝗘𝗥𝗕𝗦 & 𝗦𝗣𝗜𝗖𝗘𝗦 𝗜𝗡 𝗬𝗢𝗥𝗨𝗕𝗔

𝗡𝗔𝗠𝗘 𝗢𝗙 𝗛𝗘𝗥𝗕𝗦 & 𝗦𝗣𝗜𝗖𝗘𝗦 𝗜𝗡 𝗬𝗢𝗥𝗨𝗕𝗔

Tiger nut - Imumu/Ofio
Onion - Alubọsa
Ginger - Atalẹ
Bell pepper - Tataṣe
Garlic - Ayù
Kola nut - Obi
Cinnamon - Oriira
Walnut - Awùsá/Àsálà
Spring onion - Alubọsa Elewe
Bitter Kola - Orogbo
Basil/Mint plant - Efinrin
Bitterleaf - Ewuro
Indigo plant - Èlú (Aro)
Shea butter - Òrí
Chilli pepper/Bonnet - Ata rodo
Alligator pepper - Atare
Grape - Eso Àjàrà
Water letuce - Ojú oró
Nutmeg - Aríwó
Dates - Labidun
Bitter melon - Ejirin wewe
Eggplant - Igba/Ikan
Cayenne pepper - Ṣọmbọ
Tumeric - Ajo/Olorin (Atalẹ pupa)
Marijuana - Igbó
Corn silk - Irukere agbado
Lemon - Ijaganyin
Jute - Ewedu
Tamarind - Awin
Pumpkin - Elégédé
Lime - Osan wewe
Bamboo - Oparun
Moringa - Ewelẹ
Watermelon - Ibara
Wild lettuce  - Ẹfọ Yanrin
Cloves - Kanafuru
Breadfruit - Gbere 
Parsley - Isako
Palm kernel - Ekuro
Dates - Aran, Labidun
Beniseed - Gogo, Gorigo
Asparagus - Aluki
Velvet bean - Werepe
Locust plant - Igba
Sage - Kiriwi
Soursop - Apekan
Pigeon pea - Otiili
Custard Apple - Afon, Abo
Datura - Gegemu
Castor bean - Laara
Barbadus nut - Lapalapa
Lemon grass - Koriko oba
Starbur - Dagunro
Jack bean - Sèsé
Miracle leaf - Abamoda
Wiregrass - Ewe eran
Aloe vera - Eti Erin
Milkweed - Bomubomu
Roselle Hibiscus - Iṣapa
Cucumber - Apálá
Camwood - Osùn
Plum -Ìgọ
Hog plum - Ìyeyè
Almond - Ofio omu
Miracle berry - Agbayun
Black pepper - Iyere
Lotus plant- Oṣibata
Bush mango - Oro
Fig - Ọ̀pọ̀tọ́ (Eeya)
Siam weed - Ewe Akintola
Raffia palm - Ògùrọ
Earth chestnut - Botuje
Sugar cane - Ireke
Bush mango (seed) - Àpòn
Waterleaf - Ẹfọ Gbure
Ackee - Iṣin
Bambara nut - Ẹpa roro/Orubu
Spinach - Ẹfọ Amunututu
Amaranth/Callaloo - Ẹfọ Tete 

0 Comments